Joṣua 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún Joṣua pé, “Má bẹ̀rù wọn, nítorí pé mo ti fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́. Ẹnikẹ́ni ninu wọn kò ní lè ṣẹgun rẹ.”

Joṣua 10

Joṣua 10:4-11