Joṣua 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua bá lọ láti Giligali, òun ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀, pẹlu gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ́ akikanju ati akọni.

Joṣua 10

Joṣua 10:1-11