Joṣua 10:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua mú gbogbo àwọn ọba wọnyi, ó sì gba gbogbo ilẹ̀ wọn lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo, nítorí pé OLUWA Ọlọrun jà fún Israẹli.

Joṣua 10

Joṣua 10:40-43