Joṣua 10:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua ṣẹgun gbogbo wọn láti Kadeṣi Banea títí dé Gasa ati gbogbo agbègbè Goṣeni títí dé Gibeoni.

Joṣua 10

Joṣua 10:39-43