Jona 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ̀mí mi ń bọ́ lọ,mo gbadura sí ìwọ OLUWA,o sì gbọ́ adura mi ninu tẹmpili mímọ́ rẹ.

Jona 2

Jona 2:1-10