Johanu 9:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Juu kò gbàgbọ́ pé ó ti fọ́jú rí kí ó tó ríran títí wọ́n fi pe àwọn òbí ọkunrin náà.

Johanu 9

Johanu 9:13-20