Johanu 9:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tún bi ọkunrin afọ́jú náà pé, “Kí ni ìwọ alára sọ nípa lílà tí ó là ọ́ lójú?”Ọkunrin náà ní, “Wolii ni.”

Johanu 9

Johanu 9:10-21