Johanu 6:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí Baba alààyè ti rán mi, bẹ́ẹ̀ ni mo wà láàyè nítorí ti Baba. Ẹni tí ó bá jẹ ẹran ara mi, yóo yè nítorí tèmi.

Johanu 6

Johanu 6:47-61