Johanu 6:56 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá jẹ ẹran-ara mi, tí ó sì mu ẹ̀jẹ̀ mi, olúwarẹ̀ ń gbé inú mi, èmi náà sì ń gbé inú rẹ̀.

Johanu 6

Johanu 6:49-63