Johanu 6:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu mọ̀ pé wọn ń fẹ́ wá fi ipá mú òun kí wọ́n sì fi òun jọba, ó yẹra kúrò níbẹ̀, òun nìkan tún pada lọ sórí òkè.

Johanu 6

Johanu 6:14-22