Johanu 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu mọ̀ pé àwọn Farisi ti gbọ́ ìròyìn yìí, ó kúrò ní Judia, ó tún pada lọ sí Galili.

Johanu 4

Johanu 4:1-7