Johanu 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ṣá, kì í ṣe Jesu fúnrarẹ̀ ni ó ń ṣe ìrìbọmi fún àwọn eniyan, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ni.

Johanu 4

Johanu 4:1-12