Johanu 20:12 BIBELI MIMỌ (BM)

ó bá rí àwọn angẹli meji tí wọ́n wọ aṣọ funfun, ọ̀kan jókòó níbi orí, ekeji jókòó níbi ẹsẹ̀ ibi tí wọ́n tẹ́ òkú Jesu sí.

Johanu 20

Johanu 20:6-21