Johanu 20:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Maria dúró lóde lẹ́bàá ibojì, ó ń sunkún. Bí ó ti ń sunkún, ó bẹ̀rẹ̀ ó yọjú wo inú ibojì,

Johanu 20

Johanu 20:10-17