Johanu 19:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Jesu ti gba ọtí náà tán, ó wí pé, “Ó ti parí!”Lẹ́yìn náà ó tẹrí ba, ó bá dákẹ́.

Johanu 19

Johanu 19:23-33