Johanu 19:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwo ọtí kan wà níbẹ̀. Wọ́n bá fi kinní kan bíi kànìnkànìn bọ inú ọtí náà, wọ́n fi sórí ọ̀pá gígùn kan, wọ́n nà án sí i lẹ́nu.

Johanu 19

Johanu 19:21-38