Johanu 17:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìyè ainipẹkun náà ni pé, kí wọ́n mọ̀ ọ́, ìwọ Ọlọrun tòótọ́ kanṣoṣo, kí wọ́n sì mọ Jesu Kristi ẹni tí o rán níṣẹ́.

Johanu 17

Johanu 17:1-8