Johanu 17:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí o ti fún un ní àṣẹ lórí ẹ̀dá gbogbo, pé kí ó lè fi ìyè ainipẹkun fún gbogbo ẹni tí o ti fún un.

Johanu 17

Johanu 17:1-7