Johanu 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá ti mọ̀ mí, ẹ óo mọ Baba mi. Láti àkókò yìí, ẹ ti mọ̀ ọ́n, ẹ sì ti rí i.”

Johanu 14

Johanu 14:1-14