Johanu 14:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún un pé, “Èmi ni ọ̀nà, ati òtítọ́ ati ìyè. Kò sí ẹni tí ó lè dé ọ̀dọ̀ Baba bíkòṣe nípasẹ̀ mi.

Johanu 14

Johanu 14:5-14