Johanu 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo bá lọ pèsè àyè sílẹ̀ dè yín, n óo tún pada wá láti mu yín lọ sọ́dọ̀ ara mi, kí ẹ lè wà níbi tí èmi pàápàá bá wà.

Johanu 14

Johanu 14:1-12