Johanu 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Yàrá pupọ ni ó wà ninu ilé Baba mi. Bí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀, ǹjẹ́ n óo sọ fun yín pé mò ń lọ pèsè àyè sílẹ̀ dè yín?

Johanu 14

Johanu 14:1-3