Johanu 14:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, ẹ̀yin yóo mọ̀ pé èmi wà ninu Baba mi, ati pé ẹ̀yin wà ninu mi, èmi náà sì wà ninu yín.

Johanu 14

Johanu 14:19-30