Johanu 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Láìpẹ́, ayé kò ní rí mi mọ́, ṣugbọn ẹ̀yin yóo rí mi. Nítorí èmi wà láàyè, ẹ̀yin náà yóo wà láàyè.

Johanu 14

Johanu 14:18-22