Johanu 11:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá gbé òkúta náà kúrò. Jesu gbé ojú sókè, ó ní, “Baba, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ nítorí ò ń gbọ́ tèmi.

Johanu 11

Johanu 11:31-42