Johanu 11:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún un pé, “Ṣebí mo ti sọ fún ọ pé bí o bá gbàgbọ́ ìwọ yóo rí ògo Ọlọrun.”

Johanu 11

Johanu 11:36-42