Johanu 11:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Orí Jesu tún wú, ó bá lọ síbi ibojì. Ninu ihò òkúta ni ibojì náà wà, òkúta sì wà ní ẹnu ọ̀nà rẹ̀.

Johanu 11

Johanu 11:37-47