Johanu 11:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan ninu wọn ń sọ pé, “Ọkunrin yìí tí ó la ojú afọ́jú, ǹjẹ́ kò lè ṣe é kí ọkunrin yìí má fi kú?”

Johanu 11

Johanu 11:28-38