Johanu 1:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji, bí Jesu ti fẹ́ máa lọ sí ilẹ̀ Galili, ó rí Filipi. Ó sọ fún un pé, “Máa tẹ̀lé mi.”

Johanu 1

Johanu 1:41-47