Johanu 1:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá mú un lọ sọ́dọ̀ Jesu.Jesu tẹjú mọ́ ọn, ó ní, “Ìwọ ni Simoni ọmọ Johanu; Kefa ni a óo máa pè ọ́.” (Ìtumọ̀ “Kefa” ni “àpáta”, “Peteru” ni ní èdè Giriki.)

Johanu 1

Johanu 1:39-46