Johanu 1:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Johanu tún jẹ́rìí pé, “Mo ti rí Ẹ̀mí tí ó sọ̀kalẹ̀ bí àdàbà láti ọ̀run tí ó bà lé e, tí ó sì ń bá a gbé.

Johanu 1

Johanu 1:29-35