Johanu 1:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi alára kò mọ̀ ọ́n, ṣugbọn kí á lè fi í han Israẹli ni mo ṣe wá, tí mò ń fi omi ṣe ìwẹ̀mọ́.”

Johanu 1

Johanu 1:24-32