Johanu Kinni 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹ̀rù ninu ìfẹ́; ìfẹ́ pípé a máa lé ẹ̀rù jáde, nítorí ìjayà ni ó ń mú ẹ̀rù wá. Ẹni tí ó bá ń bẹ̀rù kò ì tíì di pípé ninu ìfẹ́.

Johanu Kinni 4

Johanu Kinni 4:13-21