Johanu Kinni 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ ṣe di pípé ninu wa, kí á lè ní ìgboyà ní ọjọ́ ìdájọ́ pé bí ó ti rí ni àwa náà rí ninu ayé yìí.

Johanu Kinni 4

Johanu Kinni 4:8-21