Jẹ́ kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè dìde,kí wọ́n wá sí àfonífojì Jehoṣafati,nítorí níbẹ̀ ni n óo ti ṣe ìdájọ́ gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó wà ní àyíká.