Ẹ yára, ẹ wá,gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè tí ẹ wà ní àyíká,ẹ parapọ̀ níbẹ̀.Rán àwọn ọmọ ogun rẹ wá, OLUWA.