Joẹli 2:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo jẹ oúnjẹ àjẹyó ati àjẹtẹ́rùn,ẹ óo sì yin orúkọ OLUWA Ọlọrun yín,tí ó ṣe ohun ìyanu ńlá fun yín,ojú kò sì ní ti àwọn eniyan mi mọ́ lae.

Joẹli 2

Joẹli 2:17-32