Joẹli 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ohun tí ẹ pàdánùní àwọn ọdún tí àwọn ọmọ ogun mi tí mo rán si yín ti jẹ oko yín;ati èyí tí eṣú wẹẹrẹ jẹ, ati èyí tí eṣú ńláńlá jẹ,gbogbo rẹ̀ ni n óo dá pada fun yín.

Joẹli 2

Joẹli 2:18-32