Joẹli 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fun fèrè ní Sioni,ẹ kéde ìdágìrì lórí òkè mímọ́ mi.Kí gbogbo àwọn tí wọn ń gbé ilẹ̀ náà wárìrì,nítorí ọjọ́ OLUWA ń bọ̀, ó sì ti dé tán.

Joẹli 2

Joẹli 2:1-10