Joẹli 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe! Ọjọ́ náà ń bọ̀,ọjọ́ OLUWA dé tán!Ọjọ́ náà yóo dé bí ọjọ́ ìparun láti ọ̀dọ̀ Olodumare.

Joẹli 1

Joẹli 1:14-17