Joẹli 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kéde ààwẹ̀, kí ẹ sì pe àpèjọ.Ẹ pe àwọn àgbààgbà, ati gbogbo àwọn tí ń gbé ilẹ̀ náà jọ sí ilé OLUWA Ọlọrun yín,kí ẹ sì kígbe pe OLUWA.

Joẹli 1

Joẹli 1:9-20