Joẹli 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Èso àjàrà ti rọ,igi ọ̀pọ̀tọ́ sì ti ń gbẹ.Igi pomegiranate, igi ọ̀pẹ ati igi ápù, ati gbogbo àwọn igi eléso ti gbẹ,inú ọmọ eniyan kò sì dùn mọ́.

Joẹli 1

Joẹli 1:10-13