Joẹli 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ banújẹ́, ẹ̀yin àgbẹ̀,ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn ẹ̀yin tí ẹ̀ ń tọ́jú ọgbà àjàrà,nítorí ọkà alikama ati ọkà baali,ati nítorí pé ohun ọ̀gbìn ti ṣègbé.

Joẹli 1

Joẹli 1:9-19