Jobu 9:34-35 BIBELI MIMỌ (BM)

34. Kí ó sọ pàṣán rẹ̀ sílẹ̀,kí ó má nà mí mọ́!Kí ìbẹ̀rù rẹ̀ má sì pá mi láyà mọ́!

35. Kí n baà le sọ̀rọ̀ láìbẹ̀rù,nítorí mo mọ inú ara mi.

Jobu 9