Jobu 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ayé sú mi,nítorí náà n kò ní dákẹ́ ìráhùn;n óo sọ̀rọ̀ pẹlu ìbànújẹ́ ọkàn.

Jobu 10

Jobu 10:1-8