Jobu 8:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Bilidadi ará Ṣuha dáhùn pé,

2. “O óo ti sọ irú ọ̀rọ̀ wọnyi pẹ́ tó,tí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ yóo sì dàbí afẹ́fẹ́ líle?

3. Ṣé Ọlọrun a máa yí ìdájọ́ po?Ṣé Olodumare a máa yí òdodo pada?

Jobu 8