Jobu 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ló dé tí ẹ kò lè dárí ẹ̀ṣẹ̀ mi jì míkí ẹ sì fojú fo àìdára mi?Láìpẹ́ n óo lọ sinu ibojì.Ẹ óo wá mi,ṣugbọn n kò ní sí mọ́.”

Jobu 7

Jobu 7:16-21