Jobu 7:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo bá ṣẹ̀, kí ni ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ṣẹ̀ yín,ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ṣọ́ mi?Kí ló dé tí ẹ fi dójú lé mi,tí mo di ẹrù lọ́rùn yín?

Jobu 7

Jobu 7:18-21