Jobu 42:16-17 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Lẹ́yìn náà Jobu tún gbé ogoje (140) ọdún sí i láyé, ó rí àwọn ọmọ ati àwọn ọmọ-ọmọ rẹ̀ títí dé ìran kẹrin.

17. Ó di arúgbó kùjọ́kùjọ́ kí ó tó kú.

Jobu 42