Jobu 42:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà Jobu tún gbé ogoje (140) ọdún sí i láyé, ó rí àwọn ọmọ ati àwọn ọmọ-ọmọ rẹ̀ títí dé ìran kẹrin.

Jobu 42

Jobu 42:15-17